Artigos
Ogum He patakori baba ocolofé jasi jasi meta meta, ogum!!!.
Pelé ogum bilé da makani um doloro
Ogum já, ogum acheque malê, ogum bii, ogum kero
Axé Ogum da ogum daxé turubaxé, ogum da Sá,
Ogum da di asivajú. Ogum yê!!!
Oriki de: Xangô
Pelé obá okossô, Tuxi kilou elerin
Obá ogodô, Obá Aganjú
Aganjú xola opou, Ibindijá omedi
Otudurê xerebinum, Obá olokum
Obá oriobou bobou, Obá kandilerin-ou
Airá inkilé, Lairá ibanã, Airá édossi
Axirá belenokó-ou, Xirê makonomim
Obanin Xangô, Sá orou Sá ojji
Agodô banin jamim, Kingodá xangô
Akiforodum labosun, Laborin axirê aja
Xirê ou fibó, Ofibó ofun marofá
Orixá ewê Kaô kabicielê!!!
Oriki de: Exú
Bará ou lokun loke
Asalanu bata bibeni jou
Olosokun alaroiê oku-ou
Abodeguá alagiri iangui
Alaketú bara-ô bi bê
Ossorokoló alabum alabum mata
Belosokun alaroiê
Exu elebará kitaxo biná
Fokun ajamim bara-ou bebê Laroiê Exú!!!
Oriki de: Iansã
Pelé yansã okedimulo, oiá degue, kilodá ilobirin, ojé olá bamitá, oiá togo, oyá duxé, oyá leiá, oya ladê.
Odiju mororum, iriku assá, alafiá diogum, firiogam, dibalé, kedu egum, kedorixá, kemaxelebó, fum abagunjá, sabilaré, alapinim, orum-bamixé, lonim abilaré, egum erajalé. Êparrei oyá!!!
Oriki de: Oxalá
Obanla o rin n'eru ojikutu s'eru. Obà n'ille Ifon alabalase oba patapata n'ille iranje. O yo kelekele o ta mi l'ore. O gba a giri l'owo osika. O fi l'emi asoto l'owo. Oba igbo oluwaiye re e o ke bi owu la. O yi ala. Osun l'ala o fi koko ala rumo. Obà igbo.
Kí Òrìsà-nlá Olú àtélesé, a gbénon dídùn là. Ní Ibodè Yìí, Kò Sí Òsán, Bèéni Kò Sí Òru. Kò Sí Òtútù, Bèéni Kò Sí Ooru. Ohun Àsírií Kan Kò Sí Ní Ibodè Yìí. Ohun Gbogbo Dúró Kedere Nínu Ìmólè Olóòrun. Àyànmó Kò Gbó Oògùn. Àkúnlèyàn Òun Ní Àdáyébá. Àdáyébá Ni Àdáyé Se.
Êpa êpa babá, Esù, Epá Babá,